chapter 7 - orí keje | let’s find something to eat!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf ·...

28
157 Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! OBJECTIVES: In this chapter you will learn: -How to express hunger and thirst -About food in the market -About daily meals -How to order food in a restaurant

Upload: trinhnga

Post on 01-Feb-2018

243 views

Category:

Documents


6 download

TRANSCRIPT

Page 1: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

157

x

Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!

OBJECTIVES:

In this chapter you will learn: -How to express hunger and thirst -About food in the market -About daily meals -How to order food in a restaurant

Page 2: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 158 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Àwæn örö (Vocabulary)

Nouns adì÷ chicken

aláköwé educated person

alárànán a type of fish

àlejò visitor, guest

àgbàdo corn

agbálùmö wild cherry

àkàrà food made from black eye peas/beans

àlùbôsà onion

àrö drum (fish)

à«áró food made from yam

ata pepper

awó guinea fowl

böölì roasted plantain

bôtà butter

búrêdì bread

dòdò fried plantain

ègbo food made from corn

èlùbô flour made from yam

èpìyà tilapia (fish)

èso fruit

ewédú a type of leafy green

ëfô leafy green

÷ja fish

÷ran meat/beef

ëgúsí melon seed

ëbà food made from cassava

ëdö liver

ëkæ a food made from corn

÷lêdë pork(pig)

÷l÷ran meat seller

÷mu palm wine

Page 3: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 159 CC – 2011 The University of Texas at Austin

ëpà peanut

ëwà beans

÷yin egg

fàájì fun

fáñtà fanta

fùfú food made from cassava

gààrí grains made from cassava

gbëgìrì bean stew

gúgúrú popcorn

hámúbôgà hamburger

ìbêp÷ papaya

ìgbákæ scoop

ìgbín snail

ìkôkærê wateryam porridge

ilá okra/okro

ìnáwó ceremony

ìpékeré plantain chips

ìsæmælórúkæ naming ceremony

ìgbéyáwó marriage ceremony

ìr÷sì/ráìsì rice

irú locust bean

ìsö stall/booth

i«u yam

iyán pounded yam/ food made from yam

kókà oòtù Quaker Oats

kídìnrín kidney

kóòkì Coca-Cola

kæfí coffee

màálù cow meat (cow)

màkàróni macaroni

máñgòrò mango

mílíìkì milk

mínírà mineral/soft drinks

môínmôín food made from black eye peas/beans

æbë stew

Page 4: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 160 CC – 2011 The University of Texas at Austin

öbökún a type of fish

ògì food made from corn

ògúfe goat meat

òkèèrè foreign

òkèlè morsel

æjô-ìbí birthday

omi water

oníbàárà customer/buyer

öpë òyìnbó pineapple

orí«irí«i different

òróró vegetable oil

æsàn orange

oúnj÷ food

panla stockfish

pàtàkì important

p÷pusí Pepsi

pæfupôöfù puff-puff (fried snack made with flour)

rárá no

tàtàsé/ tàtà«é red pepper

tíì tea

sandíìnì sardine

sêfúnæöpù 7 UP

síríàlì Corn Flakes, Rice Krispies, etc

«àkì tripe

«áwá a type of smoked fish

«íìsì cheese

«in«íìnì chinchin (fried snack made with flour)

«úgà sugar

tòlótòló turkey

tòmáàtì tomato

Noun Phrases àmàlà i«u food made from yam

àmàlàa / ækàa lááfún food made from cassava

ara ÷ran meat parts

Page 5: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 161 CC – 2011 The University of Texas at Austin

àwæn alá«æ fabric sellers

dokitæ pêpë Dr. Pepper

epo pupa palm oil

÷ja gbígb÷ dried/smoked fish

÷ja tùtú fresh fish

÷ran ìgbê bush meat

÷s÷ ÷ran cow leg

ilé-ìtajà oúnj÷ restaurant

jölôöfù ráìsì jollof rice

màmá olóúnj÷ food seller

ögëdë àgbagbà plantain

ögëdë wêwê banana

ohun-èlò oúnj÷ food ingredients

oúnj÷ olókèlè solid food (rolled into morsels)

ædún ìbílë traditional festival

ædún egúngún the masquerading festival

öbë ilá okra stew

öbë ëgúsí melon stew

ækà gidi/ àmàlà food made from yam

önà méji two ways

öpë òyìnbó pineapple

púpö nínú a lot of

rárá kògbà no deal

Verbs fêràn love/ like

fê want/ need

fún to give

gbàgbô to believe

ná shop/bargain/haggle

Verb Phrases dá lórí is about

fún mi give me

kò gbædö must not

Page 6: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 162 CC – 2011 The University of Texas at Austin

ló pö jù found the most

pín sí categorized into

rìn kæjá walk past

tún lè rí can also find/see

Adjectives èyí this

nìy÷n that

«o«o only

dára good

Adjective Phrase ju òmíràn læ than another one

Preposit ional phrases níbë there

Adverb lêëköökan once in a while

Interrogative «é ó gbà…? can I pay…?

Other Expressions bí ó ti lë jê pe in spite of the fact that

lônà mìíràn/ nígbà mìíràn in another vein/ in another light/ in other ways

ki a má gbàgbé pé don’t let us forget that

oúnj÷ tí kì í «e olókèlè food (not rolled into morsels

Page 7: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 163 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Lesson 1 - Ëkô Kìíní:

Verbs ‘fê, fêràn

Ìsöröngbèsì (Dialogue) Örê ni Túndé àti Wálé. Wálé læ kí Túndé ní ilée wæn. Túndé and Wálé are friends. Wálé visits Túndé at home.

The verb ‘fê’ means ‘to want’ while ‘fêràn’ means ‘to like or to love’.

Mo fê oúnj÷ I want food. Mo fê owó I want, or need money. Mo fê a«æ I want clothes. Mo fê j÷un I want to eat Mo fê sùn I want to sleep Mo fêràn oúnj÷ I like food. Mo fêràn owó I like, or love money. Mo fêràn a«æ I like clothes. One cannot say Mo fêràn j÷un or Mo fêràn sùn One would rather say:

Mo fêràn láti j÷un I like to eat . Mo fêràn láti sùn I like to sleep.

Page 8: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 164 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Túndé: Wálé‚ báwo ni nõkan?

Wálé: Dáadáa ni.

Túndé: Àwæn ÷bíì r÷ ñkô?

Wálé: Dáadáa ni gbogbo wôn wà o. Màmáà mi ní kí n máa kí ÷.

Túndé: Wôn mà «é o‚ wôn kú àìgbàgbé mi.

Wálé: Àwæn òbíì r÷ náà ñkô?

Túndé: Wôn ti jade láti àárö‚ kò sì y÷ kí wôn pê dé mô.

Wálé: Ó y÷ kí n dúró dè wôn‚ nítorí pé ó pê tí mo ti rí wæn.

Túndé: Kí ni kí n fi «e ê lálejò báyìí?

Wálé: Èmi! Àlejò? Gbogbo ohun tí o bá ní nílé pátá ni kí o gbé wá‚ mà á j÷ wôn. Àmô‚ má gbé ògì wá o.

Túndé: Kí ló dé?

Wálé: N kì í mu ògì. N kò fêràn ògì rárá.

Túndé: Kò burú o‚ ìr÷sì àti ëwà ni mo fê fún ÷ j÷ o.

Wálé: Ìr÷sì kë! »é kò sí iyán tàbí ëbà ní?

Túndé: Wálé! O ti fêràn òkèlè jù. Æmæ ækà!

Wálé: »é ìwæ ti gbàgbé örö àwæn Yorùbá tí wôn sæ pé: “Iyán l’oúnj÷‚ ækà l’oògùn‚ Àìrí rárá là á j’ëkæ‚ K’÷nu má dilë ni ti gúgúrú.”

Túndé: Ó dára‚ mà á fún ÷ lêbà.

Wálé: Hën-ên-ën! O «é jàre örê.

Page 9: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 165 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

True Bêë ni

False Bêë kô

1. Àwæn òbíi Túndé wà nílé ní æjô tí Wálé læ kí Túndé. ☐ ☐

2. Wálé ni ó kôkô kí Túndé. ☐ ☐

3. Kò pê tí Wálé rí àwæn òbíi Túndé. ☐ ☐

4. Túndé kò mæ Wálé rí têlë. ☐ ☐

5. Àti alê ni àwæn òbíi Túndé ti jáde. ☐ ☐

6. Gbogbo oúnj÷ tí Túndé ní ló gbé fún Wálé. ☐ ☐

7. Wálé fêràn ògì púpö. ☐ ☐

8. Ìr÷sì àti ëwà ni Túndé fún Wálé j÷. ☐ ☐

9. Wálé kò fêràn iyán. ☐ ☐

10. Àwæn òbíi Wálé mæ Túndé. ☐ ☐

I«ê »í«e 2 Lo ‘mo fêràn’ láti sæ nõkan márùnún tí o fêràn àti ìdí tí o fi fêrànan wæn. Use ‘mo fêràn’ to talk about five things you like, and state why you like them.

Bí àp÷÷r÷:

Mo fêràn owó nítorí pé mo lè fi ra ohun tí ó bá wù mi.

1.

2.

3.

4.

5.

Page 10: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 166 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Lo ‘n kò fêràn’ láti sæ nõkan márùnún tí o kò fêràn àti ìdí tí o kò fi fêrànan wæn. Use ‘n kò fêràn’ to talk about five things you do not like, and state why you do not like them.

Bí àp÷÷r÷:

N kò fêràn àìsàn nítorí pé kì í jê kí ñ «e ohun tí mo bá fê «e.

1.

2.

3.

4.

5.

Page 11: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 167 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Lesson 2 - Ëkô Kejì:

Àwæn oùnj÷ òòjô (Daily meals)

Àwæn Yorùbá fêràn oúnj÷ wönyí:

1. Môínmôín àti ògì 2. Àkàrà àti ògì 3. I«u àti ÷yin 4. ¿wà àti búrêdì 5. Dòdò àti ÷yin 6. Búrêdì àti sandíìnì 7. Búrêdì àti ÷yin 8. I«u àti æbë ata 9. Búrêdì àti bôtà 10. Síríàlì (Corn Flakes, Rice Krispies) 11. Kókà Oòtù (Quaker Oats)

1. Ëbà tàbí iyán tàbí àmàlà pëlú æbë ëgúsí tàbí ilá, tàbí ëfô, tàbí ewédú, tàbí ëfô ÷lêgùúsí

2. Ìr÷sì àti dòdò 3. Ìr÷sì àti môínmôín 4. Ìr÷sì àti ëwà 5. Ìr÷sìi jölôôfù àti adì÷/÷ran/÷ja 6. Dòdò àti ÷yin 7. Dòdò àti ëwà 8. Dòdò àti môínmôín

Oúnj÷ Æbë Èèlò æbë Èso Ìpápánu

olókèlè: ëbà, iyán, àmàlà, fùfú‚ëbà, semolina

æbë ëgúsí, ilá, ëfô, ewédú, ëfô ÷lêgùúsí

tàtàsé‚ atarodo‚ tòmáàtì‚ àlùbôsà epo pupa, irú, òroro

öp÷ òyìnbó‚ ögëdë wêwê‚ ìbêp÷‚ gúrôfà‚ æsàn‚ àgbæn‚ máõgòrò

«ínin«ìn‚ pæfupôöfù‚ ìpékeré, kókoró‚ ëpà‚ gúrúrú‚ böölì

aláìlókèlè: Ìr÷sì funfun, Ìr÷sì jölôôfù, ëwà, dodo, môínmôín, ÷yin, ògì, àkàrà, búrêdì, sandíìnì, i«u,

adì÷, ÷ran, ÷ja

ëfô: tëtë‚ «ækæ‚ ewúro‚ gbúre

Page 12: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 168 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Síse oúnj÷ ní i Ië÷ Yorùbá

Ríro iyán (Recipe for iyán) 1. Gbé ìkòkò sórí iná 2. Da omi sínú ìkòkò 3. Jê ki omi hó 4. Da iyán sínú omi híhó 5. Ro iyán nínú omi híhó fún ì«êjú márùnún sí mêwàá 6. Bí ó bá «e fê ÷ sí (ní líle tàbí ní rírö) 7. Tí ó bá le jù, fi omi díë síì 8. Tí ó bá rö jù, fi iyán díë síì 9. Dé e fún bíi ì«ëjú márùnún, tún rò ó. Ó ti jinná nìy÷n! 10. J÷ iyánàn r÷ pëlú æbë ilá tàbí æbë ëfô tàbí æbë ëfô

÷lêgùúsí. - ¿kú ìj÷un o! (Bon appetit!)

Síse æbë ÷lêgùúsí (Recipe for ëgúsí stew) 1. Læ ëgúsí pëlú omi 2. Ge àlùbôsà si wêwê 3. Da àlùbôsà sinú ëgúsí 4. Gbé ìkòkò æbë sórí iná 5. Da epo pupa sínú ìkòkò æbë 6. Tí epo pupa bá gbóná díë 7. Da àlùbôsà àti ëgúsí sínú epo pupa 8. Jê ki ó sè díë 9. Da ata lílö àti omi ÷ran sínú ìkòkò æbë 10.Ro gbogbo ë pö 11.Lêyìn ì«êjú márùnún, da ëfô gígé sínúu rë 12.Fi magí àti iyö sí i. 13.Lêyìn ì«êjú márùnún, ó ti jiná nìy÷n!

- ¿kú ìj÷un o! (Bon appetit!)

Èèlò æbë ÷lêgùúsí ( ingredients for ëgúsí s tew )

• ëgúsí • ata • omi • ëfô • epo pupa • ÷ran • omi ÷ran • iyö • àlùbôsà

Page 13: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 169 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Verbs ‘ j÷, mu’ (eat, drink)

I«ê »í«e 1 Parí àwæn örö wönyí. Complete the following sentences.

1. Fún òùngb÷, àwæn ènìyàn lè mu

2. Tí ebí bá ñ pa mí, mo lè j÷

3. Tí òùngb÷ bá ñ gb÷ mí, mo lè mu

4. Tí mo bá fê j÷ ìpápánu‚ mo lè j÷

5. Tí mo bá fê j÷ èso, mo lè j÷

Mo fê j÷ ìr÷sì. I want to eat rice. Mo fê mu omi. I want to drink water.

Mo lè j÷ ìr÷sì. I can eat rice. Mo lè mu omi I can drink water.

Page 14: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 170 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Lo örö-ì«e tó dára láti «àlàyé bí a «e le se àwæn oúnj÷ wönyí. Use the correct verb to describe how to prepare these foods.

Bí àp÷÷r÷:

se i«u

1. iyán

2. ÷yin

3. ìr÷sì jölôôfù

4. àmàlà

5. dòdò

6. ëwà

7. à«áró

8. ëbà

9. àkàrà

10. ògì

I«ê »í«e 3 Lo örö-ì«e tó dára láti «àlàyé àwæn oúnj÷ àti nõkan mímu wönyí. Use the correct verb to describe eating or drinking of the following.

Bí àp÷÷r÷:

mu omi

1. ëbà

2. ÷mu

3. kóòkì

4. àmàlà

5. ògì

Page 15: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 171 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni àwæn oúnj÷ àárö mêrin tí àwæn Yorùbá lè j÷?

2. Kí ni àwæn oúnj÷ ösán márùnún tí àwæn Yorùbá lè j÷?

3. Dárúkæ àwæn nõkan mêrin tí ìwæ máa ñ j÷ ní àárö?

4. Dárúkæ àwæn oúnj÷ mêta tí àwæn Yorùbá lè j÷ ní alê?

5. Kí ni àwæn eso mêta tí ìwæ fêràn láti j÷?

6. Kí ni àwæn æmædé fêràn láti j÷ ní ilúù r÷?

7. Kí ni àwæn æmædé fêràn láti mu ní ilúù r÷?

8. Kí ni màmáà r÷ fêràn láti j÷ ní àárö?

9. Àwæn oúnj÷ wo ni bàbáà r÷ fêràn láti j÷?

10. Àwæn èso wo ni màmáà r÷ fêràn láti j÷?

11. Kí ni àwæn nõkan tí ìwæ fêràn láti mu?

12. Àwæn èso wo ni ìwæ fêràn láti j÷?

13. Kí ni àwæn nõkan tí ìwæ lè j÷ ní ösán?

14. Kí ni àwæn nõkan tí bàbáà r÷ fêràn láti mu?

15. Kí ni àwæn nõkan tí àwæn ÷bíì r÷ lè j÷ ní alê?

Page 16: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 172 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 5 Fi èyí tó bá y÷ dí àwæn àlàfo wönyí Fill in the spaces below with appropriate pronouns.

Nígbà tí mo délé láti ilé–ìwéè mi, màmáà mi bi mí pé kí ni mo fê____________. Mo dá wæn

lóhùn pé iyán ni. Wôn sæ wipe àwæn kò lè ____________iyán ní àsìkò náà torí pé ó ti r÷

àwæn‚ «ùgbôn tí ó bá jê àmàlà ni mo fê ni, àwæn «ìlè____________ò. Màmáà

mi____________àmàlà fún mi‚ mo sì ____________ê pëlú æbë ewédú àti ÷ran. Mo fêràn

màmáà mi gan-an ni.

I«ê »í«e 6 »e àlàyé bí wôn «e máa ñ «e oúnj÷ kan nílúù r÷.

Page 17: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 173 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Lesson 3 - Ëkô K÷ta:

In the market

Ìsöröngbèsì (Dialogue)

Ìsöröõgbèsì láàárin Bùnmi àti Tósìn. (Dialogue between Bùnmi and Tósìn.)

Bùnmi: Kí ni orúkæ æjà tí wôn ñ ná ní àdúgbò tí a rìn kæjá y÷n?

Tósìn: Æjàa Sánñgo ni.

Bùnmi: »é æjà kan «o«o tí ó wà ní ìlú Ìbàdàn nìy÷n ni?

Tósìn: Rárá o!

Bùnmi: Kí ni orúkæ àwæn æjà tí ó kù àti àwæn ohun tí a lè rí rà ní ibë?

Tósìn: Orí«irí«i æjà ló wà ní ìlú Ìbàdàn yìí. Nínúu wæn ní a ti rí Æjàa Sánñgo, Æjàa Màpó, Æjà Alê«inlôyê, Æjàa Dùgbë, àti Æjà Orítamêrin. Bí àp÷÷r÷, a lè rí ohun èlò ÷nú ñ j÷ rà ní æjà Alê«ìnlôyê bí ó ti lë jê pé ìsö àwæn ála«æ ló pö jù níbë. Àwæn èlò oúnj÷ bíi ata, tòmáàtì, epo pupa, irú, òróó, àlùbôsà, ilá, ëgúsí àti oúnj÷ bíi ìr÷sì, ëwà, àgbàdo, ÷ja, ÷ran, gàrí, èlùbô, àti ëfô. A tún lè rí àwæn èso bíi æsàn, máñgòrò, ìbêp÷ àti bêë bêë læ ní àwæn æjà wönyí. Nínú àwæn æjà tí mo dárúkæ wönyí, a lè sæ wípé Æjàa Sánñgo, Màpó, àti Alê«inlôyê ni àwæn æjà tí wôn tóbi jù ní ìlú Ìbàdàn.

Bùnmi: Èyí mà dára o. Wôn yàtö púpö sí àwæn æjà tí a máa ñ ná ní Ilé-Ifë.

Page 18: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 174 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni orúkæ æjà tí Bùnmi àti Tósìn rìn kæjá?

2. Yàtö sí èlò oúnj÷ àti oúnj÷, kí ni nõkan tí a tún lè ra ni æjà Alê«inlôyê?

3. Kí ni orúkæ ìlú tí Bùnmi ti wá?

4. Orúkæ æjà mèlòó ni Tósìn dárúkæ?

5. Dárúkæ àwæn æjà tí Tósìn sæ wípé wôn tóbi jù ní ìlú Ìbàdàn?

6. Kí ni àwæn élò oúnj÷ tí a lè rà ní æjà Alê«inlôyê?

7. Dárúkæ àwæn æjà tí ó wà ní ìlúù r÷.

8. Kí ni àwæn élò oúnj÷ tí a lè rí rà ní àwæn æjà tí ó wà ní ìlúù r÷?

9. Kí ni ìdíi rë tí Bùnmi fi sæ wipé “Èyí mà dára o”?

10. Níbo ni ìlú Ìbàdàn wà?

Page 19: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 175 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Mú èyí tó bá tönà nínú àwæn wönyí. Circle the correct answer. Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê.

1. Kí ni orúkæ æjà kan tí ó wà ní ìlú Ìbàdàn tí Tósìn dárúkæ? a. Æjàa Dùgbë b. Æjà Æba c. Æjà Ilé-Ifë d. Æjà Orítamêfà

2. Kí ni wæn ñ tà ní Æjà Alê«inlôyê? a. asæ b. bàtà c. aago d. àwòrán

3. Æjà wo ni ó tóbi jù láàárin àwæn æjà tí wôn wà ní ìlú Ìbàdàn? a. Æjàa Màpó b. Æjàa Dùgbë c. Æjà Orítamêrin d. Æjà Æba

4. Kí ni orúkæ ìlú ti Tósìn ti wá? a. Ilé-Ifë b. Ìbàdàn c. Èkó d. Abêòkúta

5. Orúkæ æjà mélòó ni Tósìn dárúkæ pe wôn tóbi jù ní ìlú Ìbàdàn? a. Mêta b. Méjì c. Márùnún d. Mêfà

Page 20: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 176 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Oúnj÷ ní i lë÷ Yorùbá (Food in Yorùbá land)

Oúnj÷ olókèlè àti oúnj÷ tí kìí «e olókèlè ni önà méji pàtàkì tí àwæn oúnj÷ Yorùbá pín sí. Àwæn oúnj÷ olókèlè ni ëbà, iyán, àmàlà i«u, àmàlàa láfún àti fùfú. Àwæn oúnj÷ tí kì í «e olókèlè ni ìr÷sì, ègbo, ëwà, à«áró àti bêë bêë læ. Púpö nínú àwæn oúnj÷ olókèlè ni wôn máa ñ fi ëgê «e. Ëgê ni wôn fi ñ «e gààrí, àmàlàa láfún àti fùfú. Nínúu gààrí lati rí ëbà. Nínú i«u lati rí àmàlà i«u àti iyán. Orí«irí«i æbë ni àwæn Yorùbá máa ñ j÷. Dí÷ nínú àwæn æbë yìí ni æbë ëfô, ilá, amúnútutù, ëgúsí, ewédú àti gbëgìrì. Æbë ilá dára fún oúnj÷ òkèlè bíi ëbà. Æbë ëgúsí ni àwæn ènìyàn sáábà máa ñ fi j÷ iyán. Æbë ewédú àti gbëgìrì ni àwæn ènìyàn gbogbo sæ wípé ó dára jù fún àmàlàa láfún àti àmàlà i«u. Orí«irí«i æbë ëfô ni ó wà: æbë ëfôæ «ækæ, tëtë, gbúre, ewúro àti bêë bêë læ. Orí«irí«i ÷ran ni wôn fi ñ se æbë. Nínu àwæn ÷ran wönyí ni ÷ran ògúfe, màálù, ÷lêdë àti ÷ran ìgbê. Orí«irí«i ara ÷ran ni wôn sì ñ j÷. Nínúu wæn ni «àkì, ëdö àti kídìnrín. Àwæn Yorùbá sì máa ñ fi ÷ja se æbë nígbà mìíràn. Nínu àwæn ÷ja wönyí ni ÷ja àrö, èpìà, öbökún, alárànán, panla, «áwá àti ÷ja gbígb÷. Wôn sì tún máa ñ fi adì÷, tòlótòló, awó àti ìgbín se æbë pëlú. Yorùbá gbàgbô wípé àwæn ëyáa Yorùbá köökan fêràn oúnj÷ kan ju òmíràn læ. Bí àp÷÷r÷, àwæn Èkìtì fêràn iyán. Àwæn Ìbàdàn ni ó ni àmàlà láfún. Àwæn Ìjëbú fêranan gààrí àti ëbà. Æwô ni àwæn Yorùbá fi máa ñ sáábà j÷ òkèlè nítorí pé wôn ní ìgbàgbô pé àt÷l÷wô ÷ni kì í tan ní j÷. »ùgbôn àwæn mìíràn máa ñ fi fôökì jëun. Àwæn Yorùbá sì máa ñ j÷ èso bíi æsàn (òrombó), ìbêp÷, öpë òyìnbó, àgbálùmö àti ögëdë wêwê. Ìpápánu bíi bööli àti ëpà wà lára oúnj÷ tí àwæn ènìyàn máa ñ j÷. Böölì ni ögëd÷ tí wôn yan. Àwæn ènìyàn tun máa ñ j÷ ìpékeré, gúgúrú, ëpà àti bêë bêë læ. Ní gbogbo ìgbà ni àwæn Yorùbá máà ñ mu omi pëlú oúnj÷ wæn. »ùgbôn lêëköökan, wôn máa ñ mu mínírà bíi kóòkì, fáñtà àti p÷pusí. Nígbà mìíràn, wôn tún máa ñ mu ÷mu fún fàájì tàbí nígbà ìnáwó bíi ì«ílé, ìsæmælórúkæ, ìgbéyàwó, æjô ìbí àti ædún ìbílë bíi ædún egúngún. Ki a má gbàgbé pé àwæn Yorùbá náà máa ñ mu tíì tábí kæfí o!

Page 21: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 177 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Öná mélòó ni oúnj÷ tí àwæn Yorùbá máa ñ j÷ pín sí? 2. Kí ni àwæn oúnj÷ olókèlè? 3. Kí ni àwæn oúnj÷ tí kì í «e olókèlè? 4. Irú oúnj÷ wo ni àwæn Ìbàdàn fêràn? 5. Oúnj÷ wo ni àwæn Èkìtì fêràn? 6. Dárúkæ ìpápánu méjì tí àwæn Yorùbá máa ñ j÷. 7. Orí«i æbë mélòó ni a dárúkæ nínú àròkæ yìí? 8. Kí ni a máa ñ fi «e púpö nínú àwæn oúnj÷ olókèlè? 9. Æbë wo ni ó dára fún oúnj÷ òlókèlè? 10. Kí ni ìdíi rë tí àwæn Yorùbá fi ñ fæwô j÷un? 11. Kí ni ìpápánu tí àwæn ènìyàn máa ñ j÷ ní ìlúù r÷? 12. Kí ni àwæn oúnj÷ tí kì í «e olókèlè tí ìwæ máà ñ j÷? 13. Kí ni àwæn oúnj÷ tí ìwæ máà ñ fi æwô j÷? 14. Kí ni àwæn oúnj÷ ìlú òkèèrè tí àwæn Yorùbá máa ñ j÷? 15. lrú oúnj÷ wo ni ó y÷ kí àwæn ènìyàn máa j÷? Kí n ìdíí rë?

Page 22: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 178 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 To àwæn oùnj÷ tí o rí kà nínú àyækà yìí sí abê àwæn örö wönyí. List the various types of food or drink you read in the passage above into the groups below.

1. Oúnj÷ olókèlè:

2. Oúnj÷ tí kì í «e olókèlè:

3. Ìpápánu:

4. Nõkan mímu:

5. Æbë:

I«ê »í«e 5 To àwæn oùnj÷ tí o mö ní ìlúù r÷ sí abê àwæn örö wönyí. List the various types of food or drink in your country under the categories below.

1. Orí«irí«i ÷ja:

2. Oúnj÷ tí kì í «e olókèlè:

3. Ìpápánu:

4. Nõkan mímu:

5. Æbë:

6. Oúnj÷ àárö:

7. Oúnj÷ ösán:

8. Oúnj÷ alê:

9. Orí«irí«i ëfô:

10. Orí«irí«i ëwà:

Page 23: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 179 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 6 Kæ ìtumö àwæn örö wönyìí sílë ní èdèe Yorùbá Write down the meaning of the following expressions in Yorùbá

1. ohun-èlò ÷nú-ñ-j÷ 2. wôn yàtö 3. oúnj÷ olókèlè 4. àt÷l÷wô ÷ni kì í tan ní j÷ 5. ìsæmælórúkæ 6. ìgbéyáwó

Page 24: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 180 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Lesson 4 - Ëkô K÷rin:

Ríra oúnj÷ nínúu búkà tàbí i lé ìtajà oúnj÷.

(Ordering food in a restaurant)

Àwæn ilé ìtajà oúnj÷ alábôdé ti wà káàkiri ilë÷ Yorùbá. Àwæn oúnj÷ òkèèrè bíi meat pie, salad, chicken pie, egg buns àti bêë bêë læ, pëlú àwæn oúnj÷ ìbílë bìí iyán, ëbà àti àmàlà ni wôn ñ tà ní ilé àwæn oúnj÷ yìí. Púpö nínúu wæn wà ní ìlú ñlá bíi Èkó àti Ìbàdàn. Àwæn aláköwé ló sáábà máa ñ j÷un ní àwæn ilé oúnj÷ yìí. Díë nínú àwæn ilé oúnj÷ yìí ni Tantalizer, Mr. Biggs àti Right Choice.

Ìsöröngbèsì (Dialogue)

Oníbàárà: Màmá, irú oúnj÷ wo ni ÷ ní?

Màmá Olóúnj÷: Ëbà, iyán, ækà gidi àti fùfú.

Oníbàárà: Irú öbë wo ló wà?

Màmá Olóúnj÷: Æb÷ ilá, ëgúsí, ewédú àti gbëgìrì.

Oníbàárà: Irú ÷ran wo ló wà?

Màmá Olóúnj÷: ¿ran ògúnfe, màlúù àti öyà.

Oníbàárà: ¿ja ñ kô? Irú ÷ja wo ló wà?

Màmá Olóúnj÷: ¿ja «áwá, ÷ja èpìà, ÷ja aborí àti ÷ja àrö.

Oníbàárà: Eélòó ni ìgbákæ àmàlà kan?

Màmá Olóúnj÷: Ogúnun náírà.

Page 25: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 181 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Oníbàárà: »é ó gba náírà márùnúndínlógún?

Màmá Olóúnj÷: Rárá, kò gbà. Ogúnun náírà ni ìgbákæ.

Oníbàárà: ¿ fún mi ní ìgbakæ mêrin.

Màmá Olóúnj÷: Irú æbë wo l÷ fê? Æbë ilá, ewédú, gbëgìrì, ëgúsí àti ëfô rírò.

Oníbàárà: ¿ fún mi ní àbùlà.

Màmá Olóúnj÷: ¿rán ñkô?

Oníbàárà: Eélòó ni ÷ran köökan?

Màmá Olóúnj÷: Náírà márùnún ni ÷ran köökan.

Oníbàárà: ¿ fún mi ní ÷ran méjì?

Màmá Olóúnj÷: »é omi l÷ fê tàbí mínírà?

Oníbàárà: Irúu mínírà wo l÷ ní?

Màmá Olóúnj÷: A ní fáñtà, kóòkì, sípíráìtì, sêfúnæöpù, p÷pusí àti dôkítö p÷pë.

Oníbàárà: Eélòó ni kóòkìi yín?

Màmá Olóúnj÷: Ægbönæn náírà ni.

Oníbàárà: ¿ fún mi ní kóòkì kan. Eélòó ni owó mi jê?

Màmá Olóúnj÷: Owóo yín jê ægôfàa náírà.

Oníbàárà: ¿ gba owó.

Màmá Olóúnj÷: ¿ «é o. (Oníbàárà gba oúnj÷, ó sì wæ inúu búkà læ láti j÷ oúnj÷ rë.)

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Irú oúnj÷ wo ni màmá olóúnj÷ ní? 2. Irú nõkan mímu wo ni màmá olóúnj÷ ní? 3. Oúnj÷ wo ni oníbàárà rà? 4. Eélòó ni oníbàárà san? 5. Kí ni oníbàárà mu?

Page 26: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 182 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Lo ‘eélòó’ láti fi bèèrè iye tí wôn ñ ta àwæn oúnj÷ wönyí. Use the interrogative ‘eélòó’ to ask for the price of the following items

Bí àp÷÷r÷:

ëwà / ¥ 10 Eélòó ni ë ñ ta ëwà? Náírà mêwàá ni.

1. Ëbà àti æbë ilá / ¥150 2. Ëkæ àti môínmôín / ¥120 3. Kóòkì ìgò méjì / ¥200 4. ìr÷sì jölôöfù / ¥70 5. ìr÷sì, dòdò àti ëwà / ¥500 6. ìr÷sì, dòdò àti ÷ja / ¥600 7. iyán, æbë ëfô àti ÷ran / ¥750 8. àmàlà, æbë ewédú àti adì÷ / ¥ 690 9. búrêdì‚ ÷yin àti tíì / ¥170 10. búrêdì‚ ÷yin, tíì àti ögëdë / ¥ 190

Page 27: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 183 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Wá àwæn örö wönyí. Look for these words in the puzzle below. Pay attention to the tones! adì÷‚ àkàrà‚ àlùbôsà‚ àgbàdo‚ dòdò‚ búrêdì‚ fùfú‚ ìnáwó‚ ÷ran‚ mínírà

a f u f ú I m í n í r à d n a

b d l u ÷ g i i ÷ f u n f u d

u o ì f ÷ b n f n e w à s k i

r a n ÷ r a i u b i r í k í e

e g á a a l r f u n r e s i f

d b w s n e a u l o l a ì n u

i a ó ò ì n a w d a à d à d f

a l ì b ô s a à n ò ê h i l u

÷ r a n i l b a b r d i l o b

f ú f u n g e f ù f ú ò í a s

d o d o à l ù b ô s à d b g a

÷ b u r e d i i g b a l e u b

a k à r a m i n i r a n u e r

o k u n r i n à n m o e s n à

à b u r ê d ì a g b a d ò d o

Page 28: Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT!coerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch7.pdf · Chapter 7 - Orí Keje | LET’S FIND SOMETHING TO EAT! ... 2.Ge àlùbôsà si wêwê

Orí Keje (Chapter 7) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 184 CC – 2011 The University of Texas at Austin