external assessment sample tasks yoruba - · pdf fileexternal assessment sample tasks ... m...

13
LSPYORI/0Y07 EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA INTERMEDIATE

Upload: vudieu

Post on 01-Feb-2018

242 views

Category:

Documents


3 download

TRANSCRIPT

Page 1: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

LSPYORI/0Y07

EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKSYORUBA

INTER

MED

IATE

Page 2: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

© OCR 2010

Asset Languages

External Assessment Sample Tasks Intermediate Stage Listening and Reading

YORUBA

Contents Page

Introduction 2

Listening Sample Tasks 3

Tapescripts 5

Listening – Answer Key 7

Reading Sample Tasks 8

Reading – Answer Key 12

Page 3: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

INTRODUCTION

© OCR 2010 2

In this booklet, two sample tasks are provided for each of the skills of:

• Listening

• Reading

The two Listening and Reading Yoruba sample tasks in this booklet have been produced to give you a better idea of the style of Asset Languages Intermediate Stage External Assessment. These tasks are based on the sample external assessment materials in English on the website. Asset Languages live tests will contain tasks of the same format as the tasks provided here. For more information on the content of the Intermediate external assessments, please refer to the Introductory Stage Guide which is available on the Asset Languages website. Language specifications are also available and these show the language purposes and functions that are in external tests for each language. Asset Languages regularly receives feedback from centres and candidates as well as statistical information from candidates’ live test responses. We take this information into account and, over time, tests may be adapted and new task types introduced.

Page 4: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

LISTENING SAMPLE TASK

© OCR 2010 3

Part 2

Questions 6–10 You will hear five people talking about their plans for next weekend. For questions 6–10, listen and choose the letter (A–F) which matches each person best. There is one extra letter you do not need to use. 6 Tọpẹ A will have to finish some work.

7 Ade B is going to a family celebration.

8 Fọla C wants to buy some clothes.

9 Gani D is going to learn something new.

10 Tobi E wants to go on a city bus tour.

F will be staying on the coast.

Page 5: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

LISTENING SAMPLE TASK

© OCR 2010 4

Part 4

Questions 16–20 You will hear Bade and Nikẹ talking about the Internet. Read statements 16–20, and decide who agrees with each of them: Bade, Nikẹ or both Choose the correct answer, A, B or C. Put a tick ( ) in the box. 16 It’s better to buy books on the Internet because they’re cheaper.

A Bade B Nikẹ C both

17 Some material on the Internet needs checking for accuracy.

A Bade B Nikẹ C both

18 Our team’s website is not up to date.

A Bade B Nikẹ C both

19 It’s a good idea to use a credit card for Internet concert bookings.

A Bade B Nikẹ C both

20 The Internet is a good way of finding out the latest news.

A Bade B Nikẹ C both

Page 6: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

LISTENING SAMPLE TASK

© OCR 2010 5

R Part Two. You will hear five people talking about their plans for next weekend. For questions 6 to 10, listen and choose the letter, A to F, which matches each person best. There is one extra letter you do not need to use.

PAUSE 00’03’’ [REPEAT FROM HERE] R Six. Tọpẹ F Mo fi gbogbo ọsẹ kawe nitorina mo fẹ sinmi. Mo ti parapọ mọ awọn apọnke ti ile-iwe

giga, mo si maa ni awọn ẹkọ ni ibi ti a ya sọtọ, o ma gba mi to wakati kan pẹlu ọkọ elero. O yẹ ki ngbadun ẹ.

PAUSE 00’03’’ R Seven. Ade M Mo ma wọ ọkọ elero nla kete lẹhin is ẹ, nitorina mo ma de bẹ titi aago mejila oru. Ile

itura na wa leti omi, mo si ngbero lati kọ ọrẹ mi bi a se nluwẹ. Iyẹn yẹ ko larinrin. PAUSE 00’03’’ R Eight. Fọla F Mo nilati kọwe to ni bii ẹgbẹrun mẹfa ẹka-ọrọ ki nsi fun wọn ni owurọ ọjọ Aje, mo si

s ẹsẹ bẹrẹ ni. Awọn ẹbi mi yoku ma lọ si eti okun. O wu mi ki nle ba wọn lọ. PAUSE 00’03’’ R Nine Gani M Ọjọ ibi aburo mi ọkunrin ni ọjọ Ẹti, nitorina mo nlọ fun isinmi ni ipari ọsẹ. Awọn obi mi

fun ni kọmputa tuntun, emi na si ra ẹwu fun. A ma jade lọ jẹ ounjẹ ni aarin ilu. PAUSE 00’03’’ R Ten. Tobi F Mo ma wọ ọkọ elero lọ si igboro pẹlu ọrẹ mi. Mo nilo as ọ tuntun fun isẹ, mo si lero

wipe maa ra bata tuntun pẹlu ti ko wọn ju. O s ees e ka pade ẹgbọn ọrẹ mi obinrin fun ounjẹ ọsan.

PAUSE 00’03’’ R Now listen to Part Two again. PAUSE 00’03’’ [REPEAT PART TWO]

PAUSE 00’03’’

R That is the end of Part Two. PAUSE 00’05’’

Page 7: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

LISTENING SAMPLE TASK

© OCR 2010 6

R Part Four. You will hear Bade and Nikẹ talking about the Internet. Read statements 16 to 20 and decide who agrees with each of them: Bade, Nikẹ or both. Choose the correct answer, A, B or C. Put a tick ( ) in the box. There will be some pauses to give you time to write your answers. First, you have 10 seconds to read the statements.

PAUSE 00’10’’ [BEEP!] [REPEAT FROM HERE]

M Bawo ni Nikẹ? Mo sẹs ẹ ra awọn iwe kan lori ẹrọ ayara-bi-as a. Mo fi ọpọlọpọ owo pamọ, mi o ni lo ile-itawe mọ lai !

F Bade, iye owo kii s e koko. O se pataki lati wo iru iwe ko to ra……riraja lori ẹrọ ayara-

bi-asa kii s e fun mi.

PAUSE 00’03’’

M Sugbọn o ma nlo ẹrọ ayara-bi-asa fun iwe kika. O ni ọpọlọpọ imọ ẹri o si yara lati ri.

F O sọ otitọ nipa imọ ẹri, s ugbọn idarato rẹ le jẹ iyọnu. A ma danubi eniyan to ba ri imọ ẹri to kun fun irọ. Iyẹn ma nfani sẹhin.

PAUSE 00’03’’

M Mo ti wo ibi aaye tuntun ti ẹgbẹ ajọs ere wa lori ẹrọ ayara-bi-asa. O ni irohin to dara nipa ere, s ugbọn nkan ti mo nifẹ si ju ni gbogbo irohin nipa is ẹ awọn agbabọọlu.

F Wọn wu ni lori sugbọn ko si nkankan nipa awọn agbabọọlu tuntun kan.

PAUSE 00’03’’

M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-asa? Ẹru nba mi lati fi alaye silẹ nipa ike isanwo mi, nitorina mi o ki ns e.

F Iyẹn ko ni mi lara rara. O rọrun ati wipe o ko ni fi asiko s ofo nipa wipe a nduro lori tẹlifonu.

PAUSE 00’03’’

M Ibi ti mo ma nwo, ma nsọrọ nipa irohin agbaye. Wọn ma nparọ irohin loorekoore, o si dara gan fun iyẹn.

F Bẹẹni, ootọ ni iyẹn jẹ, s ugbọn mo s i ma nka iwe irohin pẹlu, nitoripe o ma gbọ ayẹwo orisirisi, iyẹn si s e pataki.

PAUSE 00’03’’

R Now listen to Part Four again.

PAUSE 00’03’’

[REPEAT PART FOUR]

PAUSE 00’03’’

R That is the end of Part Four.

PAUSE 00’05’’

Page 8: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

LISTENING ANSWER KEY

© OCR 2010 7

Answer Key

Part 2 6 D 7 F 8 A 9 B 10 C Part 4 16 A 17 B 18 B 19 B 20 C

Page 9: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

READING SAMPLE TASK

© OCR 2010 8

Part 4 Questions 16–20 Read the text below about a sporty chef. For each question 16–20, mark the correct letter, A, B or C, on your answer sheet.

Ere Idaraya Ati Ile Idana.

Ọpọlọpọ eniyan lero pe awọn alase ma nlo gbogbo asiko wọn ninu ile idana ti ile ounjẹ, ti o

gbona lati se ounjẹ ati lati jẹun. Sugbọn Tomi Adeagbo ko ba apejuwe yi mu. Lọmọde, o

fẹran ere sisa. Paapa ninu otutu, ti awọn olukọ rẹ ba sọ fun pe ko sare yika papa ti a ti ngba

bọọlu ni ẹẹmarun gẹgẹbi ijiya fun pe o pẹ de, Tomi kii binu rara. Kiyesi, laipẹ nigba ẹkọ kikọ ti

alase, o fẹẹ fi ere sisa silẹ nitori wahala isẹ.

Nigbati Tomi ni ile ounjẹ tiẹ, o piinu lati sare dede ko ba le wọ ẹgbẹ ti o nsare ije. Tomi ri wipe

ere sisa dede ran oun lọwọ lẹnu is ẹ. Fun wakati kan laarin pipari ounjẹ ọsan ati pipalẹmọ

ounjẹ alẹ o le ronu ati yanju iyọnu, ki o si pada bi ẹni to da ara rẹ loju.

Laipẹ yi, Tomi ti kọwe kan, ti a npe ni “Alase Ọna Okere”. Eyi wa fun awọn eniyan to fẹ mura

fun ere ije, ko si gba wọn ni iyanju lori bi a se le ni ara lile ati lati mu ipinnu wọn sẹ.

Tomi gbagbọ pe oniruuru ounjẹ yẹ ko pọ fun awọn asare ije. Wọn nilati mojuto ohun ti wọn

njẹ, sugbọn eroja oojọ ati ọpọlọpọ ounjẹ afunnilagbara maa ran wọn lọwọ. Lootọ, Tomi ma

nfun lara awọn asare ni ounjẹ ninu ile ounjẹ rẹ.

Tomi fẹ gbiyanju awọn ere sisa to gun. Awọn ọrẹ kan ti sọ fun nipa ere sisa kan ni erekusu to

rẹwa ti Réunion. Ọna ti wọn ma gba kọja pẹlu awọn oke giga kan, o si ma gba wọn ni ọjọ

mẹta. Fun Tomi, isoro ibẹ jẹ ohun ti o wu ju.

Page 10: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

READING SAMPLE TASK

© OCR 2010 9

16 When he was at school, Tomi

A preferred playing football to running.

B enjoyed running in all kinds of weather.

C found schoolwork got in the way of his running.

17 Tomi believes that running every day provides him with

A the space to think clearly about any problems.

B a much needed break from his work colleagues.

C the energy he needs to work through the evening.

18 Tomi’s book is about how to

A become a successful chef.

B prepare for a marathon race.

C achieve your ideal weight.

19 As a food expert, Tomi believes that marathon runners should

A stick to a strict calorie controlled diet.

B eat as much as they need after training.

C be aware of what they are eating.

20 Why does Tomi want to do the race on Réunion?

A He is interested in seeing such a beautiful place.

B He is keen to try something that is really challenging.

C He is sure he can complete it faster than some of his friends.

Page 11: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

READING SAMPLE TASK

© OCR 2010 10

Part 5

Questions 21–25 You are going to read an article about some scientists on a tropical island. Choose from the list (A–F) the sentence which best summarises each part (21–25) of the article. There is one extra sentence you do not need to use. Mark the correct letter A–F, on the separate answer sheet.

A The series proved that scientists need to work together.

B Scientists can always gain something positive from their failures.

C It was enormous fun to go out to a tropical island to make a television programme.

D The scientists’ lack of success is surprising, considering their background.

E There is more to this programme than pure entertainment for the audience.

F The scientists had a certain amount of equipment.

Page 12: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

READING SAMPLE TASK

© OCR 2010 11

Onimọ Ijinlẹ Mẹfa Ni Ori Erekekusu Ilẹ Ita-oorun.

21

Ere ori tẹlifisọn ti “Rough Science” yoo waye lati ọjọ Aje. Ninu eto na, wọn ko awọn onimọ-ijinlẹ sayẹnsi mẹfa lọ si ibi erekusu ilẹ Ita-oorun to mooru, wọn si ni ki wọn lo ọgbọn ati ayika wọn lati yanju orisiris i iyọnu ijinlẹ sayẹnsi. O yani lẹnu pe wọn ma nsaba kuna pẹlu gbogbo imọ wọn.

22

Tunde, ọkan ninu awọn onimọ-ijinlẹ yi s alaye pe ‘Ko si iyalẹnu kankan. Sayẹnsi jọ mọkiikuna ju yiyege lọ. Fun awọn as ewo to sis ẹ, ọpọlọpọ ni ko s isẹ – a si nkọ ẹkọ lara nkan wọnyi. Ipinnu lo s e pataki ju.’

23

Tunde sọ pe, ‘Kii s e erekus u to dahoro, – a wa ni eti ilu kan. Wọn si fun wa ni irinsẹ – kii s e nipa jija ajaye. Awọn atọkun fun wa ni awọn nkan diẹ ti a ko le ri ni inu erekusu naa, sugbọn wọn fi wa silẹ lati wa iyoku.’

24

Tunde tun fi kun wipe, ‘awọn as ewo na fihan bi sayẹnsi se jẹ akojọpọ eto. Gbogbo wa la panupọ da iyanju wa jọ, s ugbọn awọn ẹgbẹ ayaworan yari delẹ lati da si ni ọna kankan tabi gba wa niyanju lati tu awọn isoro loju.’

25

Yatọ si pe yoo jẹ ere tẹlifisọn to larinrin – ati wipe ko si iyan jija pe o ma wu ọpọlọpọ eniyan lati wo-ere yi jẹ bi ipolowo fun ipa ribiribi ti sayẹnsi nko ninu aye wa. Gẹgẹbi Tunde se sọ, idi ni yi ti o fi jẹ ohun iwuri fun olukuluku lati ni imọ to jinlẹ nipa ẹkọ yi.

Page 13: EXTERNAL ASSESSMENT SAMPLE TASKS YORUBA - · PDF fileExternal Assessment Sample Tasks ... M Njẹ o ra iwe iwọle ere ori itage ri lori ẹrọ ayara-bi-aṣa? ... For each question

READING ANSWER KEY

© OCR 2010 12

Answer Key

Part 4 16 B 17 A 18 B 19 C 20 B Part 5 21 D 22 B 23 F 24 A 25 E