l’ori awọn ilana ti ifaramo -...

29
L’ori awọn ilana ifaramo Oba Kekere Jay CI Eda Yoruba

Upload: others

Post on 03-Sep-2019

2 views

Category:

Documents


0 download

TRANSCRIPT

L’ori awọn ilana ti ifaramo

Oba Kekere Jay CI Eda Yoruba

lati owo Friedhelm Wachs || Senator # 62758European Senate President 2018/2019

Atu ede: Afelumo DamilolaLanguage: Yoruba

www.littlekingjci.com

A fe safihan agbara ti egbe JCI ni.A ni iyato to ko si nibikibi lagbaye. o ni yato si ede ti fowosi lorilede yi tii se ede geesi,ede abinibi naa wa, a lede apa tiya ati ti

baba.. E jeka safihan awon ewa ede yii. e jeka gbiyanju lati pitan kekere lawon oniruuru ede.

Yoruba Erstausgabe Titel: L’ori awọn ilana ti ifaramo© 2018 Friedhelm Wachs

Umschlag/Illustration: strichfiguren.de (Adobe Stock)Autor: Friedhelm WachsÜbersetzung: Afelumo DamilolaLektorat, Korrektorat: Sabine Schierwagen

Die deutsche Originalausgabe erschien 2018 imVerlag: Metropolis Medien Verlags GmbH, LeipzigISBN: 978-3-7479-0025-3

Das Werk, einschließlich seiner Teile, ist urheberrechtlich geschützt. Jede Verwertung ist ohne Zustimmung des Verlages und des Autors unzulässig. Dies gilt insbesondere für die elektronische oder sonstige Vervielfältigung, Übersetzung, Verbreitung und öffentliche Zugänglichmachung.

Bibliografische Information der Deutschen Nationalbibliothek:Die Deutsche Nationalbibliothek verzeichnet diese Publikation in der Deutschen Nationalbibliografie; detaillierte bibliografische Daten sind im Internet über http://dnb.d-nb.de abrufbar.

Ni igba kan ri,omo kekere kan wa to je oba. Oruko re nje Jay Citizen kini.

Jay C.I je eni to o maa n wa ninu ibanuje lati owuro titi ale.

Nigba kugba to wa wo kaakiri ayika re, gbogbo oun to ri je iwa igberaga. Ko

senikeni to nife omolakeji re denu. iwa imotaraeni nikan to wa laarin awon oba toje omode won, ti o si tun buru julo jai laarin

awon oba to je agba.Ti eleyi si sokunfa aisi idunu lokan ati igbesi aye awon oba naa.

Inu ipo buruku gbaa ni won wa!

Oba kekere Jau C.I ni o fe yi igbe aye buruku pada. Ti o si nwa ohun ti yoo se fun awon omo orilede re, paapaa julo fun awon omode egbe re, fun idokowo, fun eto eko,

fun awon to kudie kaato fun ati fun awon to wa lawon adugbo ti koti dagbasoke.

Ti o sife rerin bakan naa. O fe gbadun aye ara re, ti o si fe ko ohun titun ati nini imo

kikun nipa agbaye to rewa.

Amo o ni sugbon kan nini,bawo ni omode ara re yoo se ri gbogbo eleyi se fun ara re?

O daro ki nnkan kan to so si lokan.

O ro pe, ki lode toun o fi ba awon oba toku tawon naa fe mu ayipada deba igbesi aye

awon eniyan soro. O tesiwaju wipe kiko eko lara omolakeji ni kokoro si aseyori.

Ti o si gunle irinajo to gun lati lo sabewo sawon oba yoku.

Olori to ndun wo naa,so di mimo wipe:

Eniyan nla o ki nbeere nkan ti orilede re yoo sefun amo nkan tawon gan le se fun orilede tiwon.O ni eleyi gan lo tumo si fifife bara eni lo.O ni se eleyi, inu re

yoo si dun.

O ni asiri nla ni eleyi je. Jay C.I si tesiwaju ninu irinajo pelu idunu ati ayo.

Okurin to si apata nidi naa lo bere sini maa ko awon okuta kekeke. o ni ti a ba bere pelu igbese kan, gbogbo oke isoro yoo di petele. O ni gbogbo afojusun ajo

isokan agbaye ni yoo wa si imuse. O ni alaafia seese.

Oba nla mo wipe:

Bawo lo se rewa to! Ni oba Jay C.I she gbero wipe bibere ni kokoro si ayipada

rere..

Ti o si tun tesiwaju ninu irinajo re.

Ninu oja,ta opa eja,ma ta eja. O ni tawon eniyan ba ko biwon se npa eja, won o ko bi

won se nseranlowo fun ra won. o ni ojuse wa ni sise iranlowo fun rawa. O ni eleyi gan ni ominira. o ni awon eniyan toba lominira ni

won maa ndaboobo idajo ododo.

Oba alawo pupa gba niyanju pe:

O dara,gegebi ero okan Jay C.I , o ni o seranlowo fun oun. pelu erin lenu, oba

kekere naa tesiwaju ninu irinajo..

O ni dukia eni to sowon julo kii se awon ohun ini teniyan fowo ra,amo to je iwa owo eniyan ati iru eni teniyan naa je

gan nipato.O salaye wipe bi eniyan base ko ara re leko ni eniyan yoo se le sin

awujo daada.

Olori alawo miran wi fun wipe;

O ni kiko ara mi leko, ni gbogbo igbesi aye ni o je ohun to dun gbo. o ni eleyi yoo jeka mo nipa gbogbo awon isoro tawon omolakeji wa ndojuko. Awon oro yii ni Jay C. I nro ninu

ara re bi o se tesiwaju ninu irinajo re.

Eni nla lawujo ni o maa ndari awon eniyan pelu otito inu, lai fari apa kan dakan si, lai feran eni kan ju enikeji lo. o ni didari ni o koju osuwon ti won ba fi owo kan na ba gbogbo awon eniyan lo. O ni ki se ore ati

ibasepo lo maa nsokunfa eleyi amo ofin nikan.

Oba alawo aro mo wipe:

Eleyi lo maa nje ki ibaraenigbepo o ni itumo, ni gba ti kii sawon ore nikan lo nje gbogbo anfaani.o ni ofin kan naa lo gbodo wa fun gbogbo eniyan. o ni o je aba to dara, pelu eleyi lokan , Jay C.I tesiwaju ninu irinajo.

Oba alawo osan wi pe:

O ni nibikibi teniyan ba nlo, keniyan lo tokan tokan.pe ki eniyan maa ranti wipe ko sohunkohun to maa nti ara wa jade ati pe iwuwasi ma ni itumo nikan ta ba finu findo

she nnkan tokantokan.

Sa deede ni oba kekere Jay C.I gboju soke,ti o si ya lenu bi o ti ri aafin re lokeere. o yalenu wipe she oun ti ya sare

dele niyen?

o rin irinajo toyaya toyaya kaakiri agbaye to si ni imo kun imo kun imo.

Jay C.I ni o tete bere si ni maa samulo gbogbo imoran ati oro iyanju to ri gba lenu

awon oba ati olori naa. O wa fun awon eniyan re laanfaani lati rin irinajo ki won ba le ni iriri to ni.o ni ki won lo kaakiri agbaye, ki

won si gbadun pelu.

won wa si ile won sile ki awon eniyan ba le won bawon lalejo.ti won si fi awon ofin kan

lele ti awon alejo naa gbodo tele. tinu gbogbo won dun.

Awon oba toku wa ri wipe awon ti ri opolopo eko ko lara oba kekere Jay C.I. nu won si

dun wipe si wipe ko fi awon eko ti o ko pamo fun awon. o je ki won mo nipa gbogbo imo to rigba. Lojoojumo,ni won si nje ki igbe aye o

rorun ju tateyinwa lo.

Lojo kan, gbogbo oba naa tun pade leekan si. won jo, won yo,won si weje wemu lorumoju, ti won si ri eko ko lodo ara won.

koda, won tun so ara won loruko tiise Jaycees ti o jade lara oruko oba

kekere Jay C.I.

Nitori eso rere ti ipade won bi,won wa gbero lati

maa seto ipade apero leemeji lodun o kere tan.

Won pade lawon ape-ro agbaye, lawon eka,

lorilede ati labele nipase pipese aaye fun pasi paro.

Lakotan,won wa bori awon to ngberaga, awon eniyan nla, ati awon eniyan buruku.

Inu awon Jaycees wa dun gidi gan, ti won si mu inu awon orilede miran dun si, ti won si

dijo rerin.

Lati ara eyi ni ifaraenijin eya ti fesemule.

Gbogbo oba lo ko ero okan won sile, ti won si bere igbelaruge re.

Igbagbo wa;

• igbagbo ninu olorun ni o maa nfun igbe aye eniyan ni itumo .

• wipe wiwa eniyan ni o tayo ofin orilede.

• Wipe ododo ninu eto oro aje ni o seese nipa ni ni otito.

• Wipe ki joba o bowo fun ofin yato seniyan.

• Wipe dukia orilede to sowon julo ni o je omoniyan ati iwa omoluabi.

• Wipe isin somoniyan ni o je ise to dara ju igbesi aye eniyan.

A fe safihan agbara ti egbe JCI ni. A ni iyato to ko si nibikibi lagbaye.

o ni yato si ede ti fowosi lorilede yi tii se ede geesi, ede abinibi naa wa, a lede apa tiya ati ti baba.

E jeka safihan awon ewa ede yii. e jeka gbiyanju lati pitan kekere lawon oniruuru ede.

[email protected]

www.littlekingjci.com

ISBN: 978-3-7479-0025-3