viewchrist foundation gospel church (inc). 7, olusoji. street, orile-oshodi; p.o.box. 9. 83, mushin,...

21
CHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC) 7, Olusoji Street, Orile-Oshodi; P.O.Box 983, Mushin, Lagos State. Website: www.cfgconline.org E-Mail: [email protected] XMAS RETREAT, 2014 DAY 1 LESSON 1: (10:00 am – 12:00 pm) TOPIC: OUR REDEEMER LIVETH (JOB 19:25a) Salvation for all people He shall deliver us from all sins (Psalms 130:8) Our redeemer is mighty (Proverbs 23:11) Fear not, our redeemer will help us (Isaiah 41:14) Our redeemer, creator of all things (Isaiah 44:24) He knows us from our mother’s womb He purchased us from sins, Satan, attacks, poverty, wretchedness, sickness etc. (Isaiah 59:20) Our redeemer is strong enough to deliver us from calamity, perils, troubles, tribulation (Jeremiah 50:34) SONG: FHB 86 (CHRISTIANS LIFT YOUR VOICES IN PRAISES) 1. Christians lift your voice in praises, On this memorable day Sing in gladness, let your voices, Sing all over vale and dale Laud Hosannas, laud Hosannas,

Upload: trinhthu

Post on 06-May-2018

235 views

Category:

Documents


4 download

TRANSCRIPT

Page 1: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

CHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC)7, Olusoji Street, Orile-Oshodi; P.O.Box 983, Mushin, Lagos State.

Website: www.cfgconline.org E-Mail: [email protected]

XMAS RETREAT, 2014DAY 1

LESSON 1: (10:00 am – 12:00 pm)

TOPIC: OUR REDEEMER LIVETH (JOB 19:25a)

Salvation for all people He shall deliver us from all sins (Psalms 130:8) Our redeemer is mighty (Proverbs 23:11) Fear not, our redeemer will help us (Isaiah 41:14) Our redeemer, creator of all things (Isaiah 44:24) He knows us from our mother’s womb He purchased us from sins, Satan, attacks, poverty, wretchedness, sickness etc. (Isaiah

59:20) Our redeemer is strong enough to deliver us from calamity, perils, troubles, tribulation

(Jeremiah 50:34)

SONG: FHB 86 (CHRISTIANS LIFT YOUR VOICES IN PRAISES)

1. Christians lift your voice in praises,

On this memorable day

Sing in gladness, let your voices,

Sing all over vale and dale

Laud Hosannas, laud Hosannas,

Sea and streams all join the strain.

2. Come ye people, raise the anthem

On the earth, and heaven above

Page 2: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

All creatures above and beneath

Sing the praise of Jesus’ name

Praise Him! Praise Him!

Praise to our King born this day.

3. Sing His praises, All Africans,

Though your skin be dark or light

Sing Hosannas, laud Hosannas

Right round all our Continent,

Let every king, let every king

Prostrate fall to Christ our King.

4. Sing Hosannas, laud Hosannas

Sing aloud and shout for joy

The stronghold of Satan vanquished,

For the woman’s Seed appears

Allelujah, Allelujah,

Great Redeemer, King of kings.

5. Serraphs lift on high your voices,

With the Cherubs round the throne,

Angels and the saints in Heaven

Join with them ye heavn’ly hosts,

Rejoice with us, rejoice with us,

Year of jubilee is come.

6. Laud and honour to the Father

Laud and honour to the Son

Laud and honour to the Spirit

Three-in-One and One-in-Three

Page 3: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

Hear us and accept our praises

Thine the glory thine alone.

LESSON 2: (2:00 pm – 4:00 pm)

TOPIC: KNOWLEDGE OF OUR REDEEMER, JESUS

I know my redeemer liveth (Job 19:25a) The woman that met and know him (John 4:14) Have you been called to know him to do you good? (Romans 8:28) Life after life, we have a building of God prepared for the saved ones. (2 Corinthians 5:1;

John 14:1-3) I know whom I have believed (2 Timothy 1:12) We shall know our redeemer better when he finally reveal to us (I John 3:2) He that keepeth His commandments is dwelling in Him (I John 3:24) Not too late (Isaiah 55:6-7; 2 Corinthians 6:2) Tomorrow may be too late.

SONG: I KNOW THAT MY REDEEMER LIVETH (FHB 352)

1. I know that my Redeemer lives:

What comfort this sweet sentence gives!

He lives, He lives, Who once was dead;

He lives, my everlasting Head.

2. He lives to bless me with His love,

And still He pleads for me above;

He lives to raise me from the grave,

And me eternally to save.

3. He lives, my kind, wise, constant Friend:

Who still will keep me to the end;

He lives, and while He lives I’ll sing,

Jesus, my Prophet, Priest, and King.

Page 4: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

4. He lives my mansion to prepare;

And He will bring me safely there;

He lives, all glory to His Name!

Jesus, unchangeably the same!

5. He lives, and grants me daily breath;

He lives, and I shall conquer death:

What joy the blest assurance gives!

I know that my Redeemer lives!

DAY 2

LESSON 1: (10:00 am – 12:00 pm)

TOPIC: WE SHALL OVERCOME (REVELATION 12:11)

Our Redeemer, Jesus has overcome the world for us (John 16:33) Advice of John the beloved to all saints (I John 2:13) Greater is He that is in you (I John 4:4) Do you believe that Jesus is the son of God? (I John 5:5)

AWAITING OVERCOMERS IN HEAVEN

(a) Tree of Life (Revelation 2:7)(b) The hidden Manna (Revelation 2:17)(c) Power of the nations (Revelation 2:26)(d) White raiment for them (Revelation 3:5)(e) To expect new Jerusalem (Revelation 3:12)(f) To sit on God’s throne with our Redeemer (Revelation 3:21)

Page 5: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

(g) We shall inherit all these things (Revelations 21:7)

SONG: O COME ALL YE FAITHFUL (FHB 89)

1. O COME, all ye faithful,

Joyful and triumphant,

Come ye, O come ye to Bethlehem;

Come and behold Him

Born the King of angels:

O come let us adore Him

O come let us adore Him

O come let us adore Him, Christ the Lord

2. True God of true God,

Light of Light eternal,

Lo! He abhors not the Virgin’s womb,

Son of Father,

Begotten, not created:

O come let us adores Him, etc.

3. Sing, choirs of angels,

Sing in exaltation,

Sing, all ye citizen of heaven above,

Glory to God

All glory in the highest:

O come let us adore Him, etc.

4. Yea, Lord, we greet Thee,

Born this happy morning;

Jesus, to Thee be glory given,

Page 6: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

Word of the Father,

Now in flesh appearing:

O come let us adore Him, etc.

LESSON 2: (2:00 pm – 04:00pm)

TOPIC: THE BLOOD OF JESUS (REVELATION 12:11)

His blood is for remission of sins. (Matt. 26:28) only His blood can remove sins. To eat and drink of His blood and eat His flesh through the Lord’s supper after salvation.

(John 6:56) Spear (John 19:34) He purchased the church with His blood. (Acts 20:28) His blood delivers us from God’s anger (Romans 5:9) Reconciliation with God through His blood (Colossians 1:20) His blood cleanses us (Heb. 9:14; I John 1:7) His blood without blemish (I Peter 1:18-19) Overcomer through the blood of Jesus (Rev. 7:14; 12:11)

SONG: THE GREAT PHYSICIAN NOW IS NEAR (FHB 582)

1. The Great Physician now is near,

The sympathising Jesus;

He speak the drooping heart to cheer,

Oh, hear the voice of Jesus!

Sweetest note in Seraph song,

Sweetest name on mortal tongue,

Sweetest carol ever sung:

Jesus! Blessed Jesus!

2. Your many sins are all forgiven,

Oh, hear the voice of Jesus!

Go on your way in peace to Heaven,

And wear a crown with Jesus.

Page 7: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

Sweet note in Seraph song,

3. All glory to the risen Lamb!

I now believe in Jesus;

I love the blessed Saviour’s name,

I love the name of Jesus.

Sweet note in Seraph song,

4. His name dispels my guilt and fear,

No other name but Jesus;

Oh, how my soul delights to hear

The precious name of Jesus.

Sweet note in Seraph song,

5. Come, brethren, help me sing His praise,

Oh, praise the name of Jesus!

Come, sisters, all your voices raise,

Oh, bless the name of Jesus!

Sweet note in Seraph song,

6. The children too, both great and small,

Who love the name of Jesus,

May now accept the gracious call

To work and live for Jesus.

Sweet note in Seraph song,

7. And when to the bright world above

We rise to see our Jesus,

We’ll sing around the throne of love

Page 8: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

His name, the name of Jesus,

Sweet note in Seraph song,

DAY 3

SUNDAY SCHOOL LESSON: THE BIRTH OF JESUSTEXT: Matt 18:25; 2:1-3; Luke 2:1-40MEMORY VERSE: Fear not for behold I bring you good tidings of great joy unto us is born this day in the city of David a savior which is Christ the Lord. (Luke 2: 10-11)

1. ANGEL PROCLAMATIONi. Unto Zacharias about John the Baptist “To make ready a people prepared for the

Lord…(Luke 1:11-20)”ii. Unto Mary…Blessed art thou among women (Luke 1:26-38)

iii. Unto Joseph: “Thou shall call His name Jesus” (Matt 1:18-25)iv. Unto the Shepherds: Fear not for a savior is born…(Luke 2:8-14)

2. THE PROCLAMATION OF THE PROPHECYi. He shall be the giver of the law, from the Tribe of Judah (Gen 49:10; Luke 3:33)

ii. “…There shall be no end, upon the throne of David…” (Isaiah 9:6-7; Matt 1:1)iii. He shall be born in Bethlehem (Micah 5:2; Luke 2:1-7)iv. A Virgin shall…(Matt. 1:18-25)v. Little children shall be slained (Jer. 31:15; Matt. 2:16)

vi. Out of Egypt shall I call my son (Matt. 2:13-15; Hosea 11:1)

3. THE OCCURENCESi. There went out a decree from Ceaser Augustus, that all the world should be taxed

(Luke 1:1-3)ii. Joseph and Mary went to Bethlehem (Luke 2:4-6)

iii. Christ was born (Luke 2:7)iv. The Shepherd visited the place (Luke 2:21-24)v. Christ was brought into the Temple (Luke 2:21-24)

Page 9: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

vi. Simon saw the Savior (Luke 2:25-35)vii. Annah knew Him (Luke 2:36-38)

viii. Back to Nazareth (Luke 2:39,40)

4. THE COMING OF THE WISE MEN AND ESCAPE INTO EGYPT (MATT. 2:1-4)i. The wise men worshiped Him (Matt. 2:11,12)

ii. Arise…and flesh into Egypt (Matt. 2:13-15)iii. Herod slew all the Children (Matt. 2:16-18)iv. “Shall be called a Nazareth” (Matt. 2:19-23)

YORUBA VERSION

OJO KINI

EKO KINI: (10:00 am – 12:00 pm)

AKORI: OLUDANDE WA MBE LAAYE (JOBU 19:25A)

NITORI OLUDANDE WA MBE LAAYE:

Igbala je ti gbogbo eniyan Ohun yoo gbogbo wa lowo gbogbo ese wa (Orin Dafidi 130:8) Alagbara ni Oludande wa nse (Owe 23:11) E ma se beru Oludande wa yoo ran wa lowo (Isaiah 41:14) Oludande wa ni eleda ohun gbogbo (Isaiah 44:24) Omo wa lati inu iya wa wa. O rawa pada kuro ninu ese, Idojuko, Ise, Aini, Aisan ati bee bee lo (Isaiah 59:20) Oludande wa lagbara to lati gba wa sile ninu wahala, iji aye, idojuko ati inunibini gbogbo

(Jer. 50:34).

ORIN: FHB 86 (ONIGBAGBO E BU SAYO)

1. Onigbagbo e bu sayo

Ojo nla l’ eyi fun wa;

Page 10: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

K’orin f’ ayo korin kikan,

K’ igbo at’odan gberin,

Eho! E yo! Eho! Eyo!

Okun at’ odo gbogbo.

2. Ejumo yþ, gbogbo eda,

L’ aye yi ati l’orun;

Ki gbogbo ohun alaye

Nile loke yin Jesu,

Ef’ ogo fun, E f’ ogo fun

Oba nla t’ a bi loni!

3. Gb’ ohun nyin ga, “omo Afrik”

Enyin iran Yoruba;

Ké Hosanna! L’ ohun goro

Jake-jado ile wa.

K’oba gbogbo, K’oba gbogbo

Juba Jesu Oba wa.

4. E damusò! E damusò!

E ho yèè! K’ e si ma yo!

Itegun Èsu fo wàyi

Iru omobirin de!

Halleluya! Halleluya!

Olurapda, Oba.

5. Egb’ ohun nyin ga, Serafu,

Kerubu, leba ite;

Angeli at’ eyin mimo,

Pelu gbogb’ ogun orun,

Page 11: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

Eba wa yo! Eba wa yo!

Odun idasile de.

6. Metalokan, Eni Mimo,

Baba, Olodumare

Emi Mimo Olutunu,

Jesu, Olurapada,

Gbà iyìn wa, Gbà iyìn wa

‘Wo nikan l’ ògo ye fun.

_____________________________________________________________________________

EKO KEJI: (2:00 pm – 4:00 pm)AKORI: IMO JESU OLUDANDE WA (FHB 352)

Emi mop e Oludande mi mbe laaye (Jobu 19:25a) Obinrin ti o ba pade ti o si mo an (Johannu 4:14) Nje a ti pe o ki o le mo an ki o si se o loore? (Romans 8:28) Igbe aye wa lehin aye yi a ni ile kan ti Olorun ti pese sile fun awa eni irapada (II Korinti

5:1; Johannu 14:1-3) Emi mo eniti mo gbagbo (II Timothy 1:12) A o mo Oludande wa daradara nigbati o ba fi ara re han fun wa (I Johannu 3:2) Eniti o ba n paofin Re mo ngbe inu Re (I Johannu 3:24) Ko ti pe ju (Isaiah 55:6-7; II Korinti 6:2) Ola lee pe juu.

ORIN IJO: EMI MO PE OLUDANDE MI MBE LAYE (FHB 352)

1. “Mo mo p‘Oludande mi mbe“;

Itunu nla l’ eyi fun mi!

O mbe, Enit’ O ku lekan;

O mbe, Ori iye mi lae.

2. O mbe, lati mã bukun mi,

Page 12: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

O si mbebe fun mi l’ oke

O mbe, lati ji mi n’boji,

Lati gbà mi là titi lae.

3. O mbe, Ore kòrikòsùn,

Ti y’o pa mi mo de opin;

O mbe, emi o mã korin;

Woli, Alufa, Oba mi.

4. O mbe, lati pese àye

Y’o si mu mi de ‘be layo;

O mbe, ogo l’ oruko Re;

Jesu, Okannã titi lae.

5. O mbe, mo bolow’ aniyan;

O mbe, mo bo lowo ewu;

A! ayo l’oro yi fun mi;

“Mo mo pe’ Oludande mi mbe.”

OJO KEJIEKO KINI (10:00 am – 12:00 pm)AKORI: A O SEGUN (Ifihan 12:11)

Jesu Oludande wa ti segun aye fun wa (Johannu 16:33) Imoran Johannu Ayanfe si gbogbo eniyan mimo (I Johannu 2:13) Eniti mbe ninu yin tobi ju eniti mbe ninu aye lo (I Johannu 4:4) Nje Iwo gbagbo pe Jesu, Omo Olorun ni? (I Johannu 5:5)

Page 13: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

AWON OHUN TI O N DURO DE AWON ASEGUN NI ORUN

Igi Iye (Ifihan 2:17) Manna ti a fi pamo (Ifihan 2:17) Ase lori awon Orile ede (Ifihan 2:26) Aso funfun (Ifihan 3:5) Ireti Jerusalemu titun (Ifihan 3:12) Joko lori Ite Olorun pelu Olugbala wa (Ifihan 3:21) A o jogun awon nkan wonyi (Ifihan 21:7)

ORIN IJO: WA EYIN OLOOTO (FHB 89)

1. Wá, eyin olõoto,

L’ ayo at’ isegun,

Wá ka lo, wá kã lo si Betlehemu;

Wá ka lo wò O!

Oba awon Angel’!

E wá k’ alo jubà Re,

E wá k’ alo jubà Re,

E wá k’ alo juba

Kristi Oluwa.

2. Olodumare ni,

Imole ododo

Kò si korira inu Wundia;

Olorun papa

Ti a bi, t’ a kò dá;

E wá k’ alo jubà Re

3. Angeli, e korin,

Korin itoye Re;

Ki gbogbo edá Orun si gberin;

Page 14: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

Ògo f’olorun

L’ oke Orun lohun;

E wá k’ alo jubà Re

4. Nitooto, awole,

F’ oba t’ a bi loni;

Jesu Iwo li awa nfi ogo fun;

‘Wo Omo Baba,

T’ O gbé ara wa wo!

E wá k’ alo jubà Re

EKO KEJI (2:00 pm – 4:00 pm)

AKORI: EJE JESU (IFIHAN 12:11)

Eje Re wa fun Idariji ese (Matt. 26:28) Eje re nikan ni o le e mu ese kuro Lati je ki a si mu eje re ati eran ara re nipa jije ounje ale Oluwa lehin ti a ti ri Igbala gba

(Johannu 5:6) Oko (Johannu 19:34) Eje Re ni o si fi se Irapada Ijo (Ise Awon Aposteli 20:28) Eje Re gba wa lowo ibinu Olorun (Romu 5:9) Ilaja pelu Olorun nipa eje re ni (Kolose 1:20) Eje Re n we wa mo (Heb. 9:14; I Johannu 1:7) Eje ti ko labawon (I Peteru 1:18-19) Asegun nipa eje Jesu (Ifihan 7:14; 12:11)

ORIN IJO: ONISEGUN NLA WA NIHIN (FHB 582)

1. Onisegun nla wa nihin,

Jesu abanidarò;

Oro Re mu ni l’ ara da,

A! gbo ohun ti Jesu;

Iro didun l’ orin Seraf’,

Page 15: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

Oruko didun n’nu enia,

Orin t’o dun julo ni,

Jesu, Jesu, Jesu.

2. A fi gbogb’ ese re ji o;

A! gbo ohun ti Jesu!

Rin lo s’ Orun l’alafia,

Si ba Jesu de ade.

Iro didun l’orin Seraf’ &c.

3. Gbogb’ ogo fun Krist’ t’ O jinde;

Mo gbagbo nisisiyi;

Mo f’ oruko Olugbala,

Mo f’oruko Jesu.

Iro didun l’orin Seraf’ &c.

4. Oruko Re l’ eru mi lo;

Ko si oruko miran;

B’ okan mi ti nfe lati gbo

Oruko Re ‘yebiye!

Iro didun l’orin Seraf’ &c.

5. Arakunrin, e ba mi yin In

A, yin oruko Jesu;

Arabinrin, gb’ ohùn s’oke,

A, yin oruko Jesu.

Iro didun l’orin Seraf’ &c.

6. Omode at’ agbalagba,

Page 16: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

T’ o fe oruko Jesu,

Le gba ‘pe ‘fe nisisiyi

Lati sise fun Jesu.

Iro didun l’orin Seraf’ &c.

7. Nigbat’ a ba si de Orun,

Ti a ba si ri Jesu,

Ao ko ‘rin y’ ite ife ka,

Orin Oruko Jesu.

Iro didun l’orin Seraf’ &c.

OJO KETAEKO OJO ISIMI: IBI JESU

IBI KIKA: Matteu 18:25; 2:1-23; Luku 2: 1-40

AKOSORI: “Ma beru: sawo o, mo mu ihinrere ayo nla fun yin wa, ti yio se ti eniyan gbogbo. Nitori a bi Olugbala fun yin lonini ilu Dafidi, ti ise Kristi Oluwa” (Luku 2:10-11)

1. IKEDE ANGELIi. Fun Sekariah nipa Johannu Baptisi: “Oun o pese eniyan sile” (Luku 1:11-20)ii. Si Maria: “Alabukun fun ni iwo ninu awon Obinrin” (Luku 1: 26-38)iii. Si Josefu: “Jesu ni iwo o pe oruko Re” (Matt. 1:18-25)iv. Si awon Oluso Agutan: Ma beru…A bi Olugbala fun nyin (Luku 2:18-14)

2. AWON AKEDE SOTELEi. Ohun yoo je Olorun lati inu eya Juda (Genesisi 49:10; Luku 3:33)ii. Arole lori ite Dafidi yoo joba titi lai (Isaiah 9:6,7; Matt. 1:1)iii. A o bi ni Bethlehemu, (Mika 5:2; Luku 2:1-7)iv. Wundia kan yi o “Bi omokunrin kan” (Isaiah 7:14; Matt. 1:18-25)v. A o pa awon omo were, (Jer. 31:15; Matt. 2:16)vi. “Ni Egipti ni mo ti pe omo mi jade wa” (Matt 2:13-15; Hosea 11:1).

3. AWON OHUN TI O SELE

Page 17: viewCHRIST FOUNDATION GOSPEL CHURCH (INC). 7, Olusoji. Street, Orile-Oshodi; P.O.Box. 9. 83, Mushin, Lagos State. Website: . E-Mail: info@cfgconline.org

i. Kesari Augustu pase ki a ko Oruko gbogbo aye sinu Iwe (Luku 2:4-6)ii. Josefu ati Maria lo si Bethlehemu (Luku 2:4-6)iii. A bi Jesu si Ibuje Eran. (Luku 2:7)iv. Awon Oluso Agutan was i Ibuje Eran (Luku 2: 8-20)v. A gbe Jesu wa si Tempili (Luku 2:25-35)vi. Anna wo Oludande (Luku 2:36-38)vii. Ipada lo won si Nasareti (Luku 2: 39-40)

4. WIWA AWON AMOYE ATI SISALO SI EGIPTIi. “Kiyesi, awon amoye kan ti Ila-Orun was i Jerusalemu” (Matt 2:1-4)ii. Irawo na siwaju won lo (Matt. 2:5,10)iii. Awon Amoye na juba Jesu (Matt. 2:13-15)iv. Herodu pa gbogbo omo were ni Bethlehemu (Matt. 2:16-18)v. “A o pe ni ara Nasareti” (Matt. 2:19-23).